Song Page - Lyrify.me

Lyrify.me

...And So She Spoke... by Laycon Lyrics

Genre: pop | Year: 2021

[Intro]
Olamilekan Adisa, omo agbe le she bi oba
Oko mi Adisa, wa lalubarika
Aburu o ni je ti e, inshallah, wa rire
Ire owo, ire omo, ire alafia see
Aburu o ni je ti e, bo nshe toju mi, ma si ke iwo no o
Oke oke oke oke bayi ni ola e ma lo o ni jabo
Gbogbo ibi kibi to ma te bayi, adun adun adun ni wa mari
Gbogbo gba ti wa ba fe iyawo o ni shi ma bamu
Tira wo yin a jo papo, te n ma she nkan mere mere te da se ni aye
Oshe, modupe dupe o, wa sho rire, wa lalubarika o
Ire ni ti ti e o, ire ti tawon egbon e no o
Olamilekan Adisa, of La La La, of Laycon, awa fierce
Fiеrce nation o ni to le o, o ma ma gboro ni
A gboro kakiri ori dun merеrin agbaye
Inshallah, la la hawla wala quwwata illa billah ill adhim
La Al Fatihah
Bismillaahir Rahmaanir Raheem
Alhamdu lillaahi Rabbil 'aalameen
Ar-Rahmaanir-Raheem
Maaliki Yawmid-Deen
Iyyaaka na'budu wa lyyaaka nasta'een
Ihdinas-Siraatal-Mustaqeem
Siraatal-lazeena an'amta 'alaihim ghayril-maghdoobi 'alaihim wa lad-daaalleen
Ameen, ameeen, Subhana rabbika rabbil 'izzati amma yasifun wa salamun alal mursalin wal hamdulillahi rabbil 'alamin
Adun adun adun bayi ni wa ma ri
Olamilekan Adisa, omo ade le se bi oba